Yoruba

BBC News, Yorùbá - Ìròyìn

BBC News, Yorùbá - Ìròyìn

Ìròyìn tó ṣe kókó

  • Ta ni Idiat Adebule, aṣòfin Eko tó jáde láyé?Ni ọjọ Abamẹta, ọjọ Kejidinlogun, oṣu Kọkanla, ọdun 2026 ni Adebule jade laye.28 Bélú 2026
  • Pete Edochie: Bí òṣèré nínú eré 'Things Fall Apart' ṣe di gbajúmọ̀ òṣèré lágbo tíátàKí o tó di gbajúmọ̀ ni gbogbo ilé àti lágbo òṣèré tíátà nílẹ̀ Nàìjíríà, Edochie tí koko ṣe iṣẹ́ aáyán láàyò nídìí ìṣẹ agbohunsafẹfẹ 28 Bélú 2026
  • NÍ YÀJÓYÀJÓ , Kí ni ó bí ètò ìdìbò ìgbáradì tó ń lọ lọ́wọ́ lónìí ní Nàìjíríà?Ìròyìn àtìgbàdégbà nípa ìdìbò ìgbáradì INEC ṣáájú ètò ìdìbò ọdún 2027
  • Ìjọba ológun yí àdéhùn padà ní Guinea-Bissau, wọ́n ló di 2028 káwọn tóó gbé ìjọba fún alágbádáNinu ikede ti Gen Horta N'Tam, aarẹ ologun to n dari orilẹede naa ṣe lo ti ni ibo to yẹ ko waye lọjọ kẹfa oṣu Kejila yii ko ni I waye mọ.28 Bélú 2026
  • Wo awọn ọmọ Naijiria 157 ti ijọba Amẹrika fẹẹ da pada sile lori ẹsun iwa ọdaranAwọn ohun to nii ṣe pelu iwa jibiti owo, gbigbe owo rin lọn aitọ, gbigbe egboogi oloro, ilọnilọwọgba, ati iwa ipa si ọmọde ni wọn fi kan gbogbo awọn eeyan naa.28 Bélú 2026
  • Ohun tó yẹ kí o mọ̀ nípa ìdìbò ìgbáradì tí INEC ń ṣe lónìíOni ọjọ Satide, ọjọ kejidinlọgbọn oṣu Kọkanla ọdun 2026 ni eto idibo ìgbáradì náà n waye, o jẹ́ ara ìmúrasílẹ̀ fún idibo ọdún 2027.28 Bélú 2026
  • Ohun márùn ún ọ̀tọ̀tọ̀ tí Adeleke ní òun yóò ṣe fún ìpínlẹ̀ Osun ní sáà kejì rẹ̀ lórí oyèAdeleke lo sọrọ yii lasiko ti wọn burawọle fun fun saa keji niluu Osogbo.28 Bélú 2026
  • 2:26Fídíò, Mo fẹ́ di ológo nlá lágbo olórin lọ́dún méjì sí àsìkò yìí - Magixx, Duration 2,26Magixx tun sọ fun BBC News Yoruba wi pe oun fẹran obinrin gan an ,amọ, o ni iwọntunwọnsi naa ni gbogbo nnkan.28 Bélú 2026
  • Ẹ gba àlàáfíà láàyè, máà fún ẹbí olóògbé kọ̀ọ̀kan ní mílíọ̀nù méjì Náírà - Gómìnà Bago ti NigerYatọ si wi pe wọn pa Baalẹ Muhammad atawọn ẹbi re, awọn eeyan naa tun dana sun aafin rẹ, leyi to mu kawọn ti ori ko yọ sa asala fun ẹmi ara wọn.28 Bélú 2026
  • Àyájọ́ ọjọ́ aṣọ Òfì, láìsí ìrànlọ́wọ́ ìjọba; aṣọ òfì lè parun láìpẹ́27 Bélú 2026
  • Iyabo Ojo ń bọ àwọn ọba alayé lọ́wọ́ lóde àríyá, Ọba kan kọ̀ láti bọ ọwọ́, ariwo bá sọ lórí ayélujáraIyabo Ojo ń bọ àwọn ọba alayé lọ́wọ́ lóde àríyá, Ọba kan kọ̀ láti bọ ọwọ́, ariwo bá sọ lórí ayélujára27 Bélú 2026
  • 1:00Orin, Kò ṣe é má gbọ̀ ọ́, Duration 1,00Àkójọpọ̀ ìròyìn káàkiri àgbáyé tí kò ṣe è má gbọ̀ ọ́27 Bélú 2026

Ta ni Idiat Adebule, aṣòfin Eko tó jáde láyé?

Ni ọjọ Abamẹta, ọjọ Kejidinlogun, oṣu Kọkanla, ọdun 2026 ni Adebule jade laye.

Pete Edochie: Bí òṣèré nínú eré 'Things Fall Apart' ṣe di gbajúmọ̀ òṣèré lágbo tíátà

Kí o tó di gbajúmọ̀ ni gbogbo ilé àti lágbo òṣèré tíátà nílẹ̀ Nàìjíríà, Edochie tí koko ṣe iṣẹ́ aáyán láàyò nídìí ìṣẹ agbohunsafẹfẹ

NÍ YÀJÓYÀJÓ , Kí ni ó bí ètò ìdìbò ìgbáradì tó ń lọ lọ́wọ́ lónìí ní Nàìjíríà?

Ìròyìn àtìgbàdégbà nípa ìdìbò ìgbáradì INEC ṣáájú ètò ìdìbò ọdún 2027

Ìjọba ológun yí àdéhùn padà ní Guinea-Bissau, wọ́n ló di 2028 káwọn tóó gbé ìjọba fún alágbádá

Ninu ikede ti Gen Horta N'Tam, aarẹ ologun to n dari orilẹede naa ṣe lo ti ni ibo to yẹ ko waye lọjọ kẹfa oṣu Kejila yii ko ni I waye mọ.

Wo awọn ọmọ Naijiria 157 ti ijọba Amẹrika fẹẹ da pada sile lori ẹsun iwa ọdaran

Awọn ohun to nii ṣe pelu iwa jibiti owo, gbigbe owo rin lọn aitọ, gbigbe egboogi oloro, ilọnilọwọgba, ati iwa ipa si ọmọde ni wọn fi kan gbogbo awọn eeyan naa.

Ohun tó yẹ kí o mọ̀ nípa ìdìbò ìgbáradì tí INEC ń ṣe lónìí

Oni ọjọ Satide, ọjọ kejidinlọgbọn oṣu Kọkanla ọdun 2026 ni eto idibo ìgbáradì náà n waye, o jẹ́ ara ìmúrasílẹ̀ fún idibo ọdún 2027.

Ohun márùn ún ọ̀tọ̀tọ̀ tí Adeleke ní òun yóò ṣe fún ìpínlẹ̀ Osun ní sáà kejì rẹ̀ lórí oyè

Adeleke lo sọrọ yii lasiko ti wọn burawọle fun fun saa keji niluu Osogbo.

Fídíò, Mo fẹ́ di ológo nlá lágbo olórin lọ́dún méjì sí àsìkò yìí - Magixx, Duration 2,26

Magixx tun sọ fun BBC News Yoruba wi pe oun fẹran obinrin gan an ,amọ, o ni iwọntunwọnsi naa ni gbogbo nnkan.

Ẹ gba àlàáfíà láàyè, máà fún ẹbí olóògbé kọ̀ọ̀kan ní mílíọ̀nù méjì Náírà - Gómìnà Bago ti Niger

Yatọ si wi pe wọn pa Baalẹ Muhammad atawọn ẹbi re, awọn eeyan naa tun dana sun aafin rẹ, leyi to mu kawọn ti ori ko yọ sa asala fun ẹmi ara wọn.

Àyájọ́ ọjọ́ aṣọ Òfì, láìsí ìrànlọ́wọ́ ìjọba; aṣọ òfì lè parun láìpẹ́

Iyabo Ojo ń bọ àwọn ọba alayé lọ́wọ́ lóde àríyá, Ọba kan kọ̀ láti bọ ọwọ́, ariwo bá sọ lórí ayélujára

Orin, Kò ṣe é má gbọ̀ ọ́, Duration 1,00

Àkójọpọ̀ ìròyìn káàkiri àgbáyé tí kò ṣe è má gbọ̀ ọ́

Móríwú

  • 02:22 Fídíò, Àyànmọ́ ni bí mo ṣe kúrò ní ààfin Ooni - Olorí Naomi, Duration 2,22
  • 01:41 Fídíò, Olúwa ló darí Ooni sí mi, ìdí iṣẹ́ ìráńṣẹ́ ni wọ́n ti pàdé mi - Naomi Ogunwusi, Duration 1,41
  • 02:29 Fídíò, Ẹ̀kọ́ ọ̀fẹ́ 20 ni mo kọ̀wé fún, ṣùgbọ́n mẹ́rin péré ni mo rí gbà - Akẹ́kọ̀ọ́ tó gba First Class, Duration 2,29
  • 02:29 Fídíò, Inú mi kò dùn nígbà tí Taiwo mi ṣe ìgbéyàwó torí ó dà bí ẹni pé wọ́n gba ìyàwó mi ni - Kehinde Afolabi, Duration 2,29
  • 02:30 Fídíò, "Ìgbà mẹ́rin ọ̀tọ̀ọ̀tọ̀ ni mo ti kó sọ́wọ́ ajínigbé, ohun tí ojú mí rí rèé", Duration 2,30
  • 02:32 Fídíò, Àwọn ohun tí mo là kọjá ló tọ́ mi sọ́nà tí mò ń tọ̀ báyìí - Dieko, ọmọ Kunle Afolayan sọ̀rọ̀, Duration 2,32
  • 02:28 Fídíò, AI ni wọ́n fi ṣe fọ́tò mi pé mo ṣe ìpàdé pẹ̀lú Sheik Gumi, n kò sí níbi ìpàdé náà - Oriyomi Hamzat, Duration 2,28
  • 02:29 Fídíò, Ibi tí wọ́n bí mi sí kò jìnà síbi tí wọ́n ti ń ta igbó, àánú ló kó mi yọ tí mo fi di akọrin ẹ̀mí - Esther Igbekele, Duration 2,29
  • 02:27 Fídíò, Kò sóhun tó burú níbẹ̀ bí obìnrin bá ṣe ìyàwó kejì, ìkẹ́ta tàbí ìkẹ́rin nílé ọkọ- Wasila Coded, Duration 2,27
  • 02:35 Fídíò, Onídìrí àti Púlọ́ńbà ni àwọn òbí mi àmọ́ mo ní ìpínnu pé mo gbọ́dọ̀ tayọ - Akẹ́kọ̀ọ́jáde tọ tayọ, Duration 2,35
  • 02:11 Fídíò, Inu owó ata àti ẹran tí ìyá àti bàbá mi ń tà ni wọ́n ti ṣàtìlẹ́yìn fún mi láti gbá bọ́ọ̀lù- Bashiru Awawu, agbábọ́ọ̀lù Flamigoes, Duration 2,11
  • 02:32 Fídíò, Abacha pinnu láti pa mí sí àhámọ́ àmọ́ Jimmy Carter kéde pé tí mo bá kú, Abacha náà yóò kú - Obasanjo, Duration 2,32

Ìparí Móríwú

BBC News Yorùbá ti wà lórí ìkànnì WhatsApp

Má jẹ́ kí etí rẹ ó di sí gbogbo ìròyìn ohun tó ń lọ ní Naijiria àti káàkiri àgbáyé. Mọ̀ nípa wọn lórí ìkànnì Whatsapp rẹ

Ìròyìn Àkàgbádùn

  • Fídíò, Olorì Naomi Silekunola sọ̀rọ̀ nípa ìgbé ayé rẹ̀ bíi aya ọba, akẹ́kọ̀ọ́ àti òjíṣẹ́ Olúwa, Duration 26,39Lórí eto Bo se n lọ, Olorì Naomi Silekunola sọ̀rọ̀ nípa ìgbé ayé rẹ̀ bíi aya ọba, akẹ́kọ̀ọ́ àti òjíṣẹ́ Olúwa27 Bélú 2026
  • Mi ò fẹ yín, bẹ́ẹ̀ ni mi ò fìwé pè ẹ̀yin ọmọ ẹgbẹ́ awakọ̀ NURTW síbi ìbúrawọlé mi - Gomina Ademola AdelekeỌrọ yii ko sẹyin wahala ati rogbodiyan ija garaaji n to waye lemọlemọ nipinlẹ Ọsun. 27 Bélú 2026
  • Wo àwọn àsìkò tí ìwa ipá ti ṣẹlẹ̀ káàkiri Nàíjíríà látìgbà tí ọ̀rọ̀ ètò ìdìbò 2027 ti bẹ̀rẹ̀Ninu oṣu kẹjọ, ọdun yii ni ajọ eleto idibo nilẹ Naijiria, INEC ranṣẹ pe gbogbo awọn oludije, to fi mọ awọn alakoso ẹgbẹ oṣelu kọọkan, lati tọwọ bọwe adehun wi pe wọn yoo gba alaafia laaye ni gbogbo asiko ipolongo ibo ati ọjọ idibo.27 Bélú 2026
  • Ilé ejọ́ pàṣẹ kí wọ́n fi òfin gbé Jimmy Odukoya wá sílé ẹjọ́26 Bélú 2026
  • ''Olorì lè kúrò ní àáfin àmọ́ ààfin kìí fi Olorì sílẹ̀,'' Olorì Silekunola sọ̀rọ̀ lórí i bó ṣe pàdé kábíyèsí àti bó ṣe kúrò láàfin Ooni Olori Naomi Silekunola sọ pe ''aditu ni ọrọ bi mo ṣe pade Ooni, eeyan kii tu u, Oluwa lo dari Ooni si mi.''26 Bélú 2026
  • Ìgbà mẹ́ta ọ̀tọ̀tọ̀ ni mo rí Satani, mo tún rí ẹnu ọ̀nà ọ̀run àpáàdì – Pope FrancisỌrọ naa lo jẹyọ ninu akọsilẹ rẹ ti wọn ṣẹṣẹ ko jade.26 Bélú 2026
  • Adebayo Salami, Joke Silva ṣèdárò àgbà òṣèré Pete Edochie tó jáde láyéAgba oṣere Adebayo Salami kẹdun Pete Edochie loju opo Instagram rẹ pe ''gbogbo nnkan ni asiko wa fun un. Asiko lati gbe ile aye ati asiko lati fi ile aye silẹ, gbogbo rẹ lo si ni idi.'' 26 Bélú 2026
  • Ọta ìbọn ba ọ̀dọ́bìnrin yìí lójú lọ́mọ ọdún 15: Ọ̀pọ̀ ẹ̀mí ló ti ṣòfò báwọn ọmogun ajìjàgbara ṣe ń kọjú ìjà síjọbaO kere tan, Median ti ṣe iṣẹ abẹ merin ni Cameroon, Ghana ati India lori ojú rẹ laarin odun mẹjọ seyin.25 Bélú 2026
  • Ìjọba ìpínlẹ̀ Katsina dá Emir Daura dúró lórí ẹ̀sùn fífi ọwọ́ kan obìnrin arìnrìnàjò lọ́nà àìtọ́Aṣẹ to da Emir naa duro sọ pe ko gbọdọ kopa ninu gbogbo ohun to ba jẹ mọ iṣakoso, bẹẹ ni ko gbọdọ rin awọn irinajo kan mọ.25 Bélú 2026
  • Ilé ẹjọ́ yọ Omo-Agege gẹ́gẹ́ bíi olùdíje NDC fún ilé ìgbìmọ̀ aṣòfin DeltaIgbẹjọ naa, ti adajọ Hyeladzira Ajiya Nganjiwa gbe kalẹ rẹ sọ pe bi wọn ṣe fa Omo-Agege kalẹ lati ṣoju ẹgbẹ naa ko ba ilana idibo mu.25 Bélú 2026
  • Ta ni Balogun Agba ilu Ilorin, Alhaji Aliyu Adebayo Balogun tó dágbéré fáyé?25 Bélú 2026
  • 'Scholarship 20 ni mo kọ̀wé fún, ṣùgbọ́n mẹ́rin péré ni mo rí gbà' - Akẹ́kọ̀ọ́ First ClassNigba to n ba BBC sọrọ, ọmọbinrin naa ṣalaye irin ajo rẹ, ati bo ṣe tiraka lati de ipo naa, pẹlu afojusun rẹ lẹyin ọdun marun-un si asiko yii.25 Bélú 2026

Fídíò, Olorì Naomi Silekunola sọ̀rọ̀ nípa ìgbé ayé rẹ̀ bíi aya ọba, akẹ́kọ̀ọ́ àti òjíṣẹ́ Olúwa, Duration 26,39

Lórí eto Bo se n lọ, Olorì Naomi Silekunola sọ̀rọ̀ nípa ìgbé ayé rẹ̀ bíi aya ọba, akẹ́kọ̀ọ́ àti òjíṣẹ́ Olúwa

Mi ò fẹ yín, bẹ́ẹ̀ ni mi ò fìwé pè ẹ̀yin ọmọ ẹgbẹ́ awakọ̀ NURTW síbi ìbúrawọlé mi - Gomina Ademola Adeleke

Ọrọ yii ko sẹyin wahala ati rogbodiyan ija garaaji n to waye lemọlemọ nipinlẹ Ọsun.

Wo àwọn àsìkò tí ìwa ipá ti ṣẹlẹ̀ káàkiri Nàíjíríà látìgbà tí ọ̀rọ̀ ètò ìdìbò 2027 ti bẹ̀rẹ̀

Ninu oṣu kẹjọ, ọdun yii ni ajọ eleto idibo nilẹ Naijiria, INEC ranṣẹ pe gbogbo awọn oludije, to fi mọ awọn alakoso ẹgbẹ oṣelu kọọkan, lati tọwọ bọwe adehun wi pe wọn yoo gba alaafia laaye ni gbogbo asiko ipolongo ibo ati ọjọ idibo.

Ilé ejọ́ pàṣẹ kí wọ́n fi òfin gbé Jimmy Odukoya wá sílé ẹjọ́

''Olorì lè kúrò ní àáfin àmọ́ ààfin kìí fi Olorì sílẹ̀,'' Olorì Silekunola sọ̀rọ̀ lórí i bó ṣe pàdé kábíyèsí àti bó ṣe kúrò láàfin Ooni

Olori Naomi Silekunola sọ pe ''aditu ni ọrọ bi mo ṣe pade Ooni, eeyan kii tu u, Oluwa lo dari Ooni si mi.''

Ìgbà mẹ́ta ọ̀tọ̀tọ̀ ni mo rí Satani, mo tún rí ẹnu ọ̀nà ọ̀run àpáàdì – Pope Francis

Ọrọ naa lo jẹyọ ninu akọsilẹ rẹ ti wọn ṣẹṣẹ ko jade.

Adebayo Salami, Joke Silva ṣèdárò àgbà òṣèré Pete Edochie tó jáde láyé

Agba oṣere Adebayo Salami kẹdun Pete Edochie loju opo Instagram rẹ pe ''gbogbo nnkan ni asiko wa fun un. Asiko lati gbe ile aye ati asiko lati fi ile aye silẹ, gbogbo rẹ lo si ni idi.''

Ọta ìbọn ba ọ̀dọ́bìnrin yìí lójú lọ́mọ ọdún 15: Ọ̀pọ̀ ẹ̀mí ló ti ṣòfò báwọn ọmogun ajìjàgbara ṣe ń kọjú ìjà síjọba

O kere tan, Median ti ṣe iṣẹ abẹ merin ni Cameroon, Ghana ati India lori ojú rẹ laarin odun mẹjọ seyin.

Ìjọba ìpínlẹ̀ Katsina dá Emir Daura dúró lórí ẹ̀sùn fífi ọwọ́ kan obìnrin arìnrìnàjò lọ́nà àìtọ́

Aṣẹ to da Emir naa duro sọ pe ko gbọdọ kopa ninu gbogbo ohun to ba jẹ mọ iṣakoso, bẹẹ ni ko gbọdọ rin awọn irinajo kan mọ.

Ilé ẹjọ́ yọ Omo-Agege gẹ́gẹ́ bíi olùdíje NDC fún ilé ìgbìmọ̀ aṣòfin Delta

Igbẹjọ naa, ti adajọ Hyeladzira Ajiya Nganjiwa gbe kalẹ rẹ sọ pe bi wọn ṣe fa Omo-Agege kalẹ lati ṣoju ẹgbẹ naa ko ba ilana idibo mu.

Ta ni Balogun Agba ilu Ilorin, Alhaji Aliyu Adebayo Balogun tó dágbéré fáyé?

'Scholarship 20 ni mo kọ̀wé fún, ṣùgbọ́n mẹ́rin péré ni mo rí gbà' - Akẹ́kọ̀ọ́ First Class

Nigba to n ba BBC sọrọ, ọmọbinrin naa ṣalaye irin ajo rẹ, ati bo ṣe tiraka lati de ipo naa, pẹlu afojusun rẹ lẹyin ọdun marun-un si asiko yii.

Ìròyìn Pàtàkì

  • Ilé ẹjọ́ CAS kéde Senegal gẹ́gẹ́ bí ẹgbẹ́ agbábọ́ọ̀lù tó gba ife ẹ̀yẹ AFCON 2025, Morocco mófo24 Bélú 2026
  • A ti kẹ́fín pé àwọn Janduku fẹ́ lo ìpinnu wa fi dá wàhálà sílẹ̀-NURTW Oyo23 Bélú 2026
  • Gbajúmọ̀ òṣèré Anike Sinleke jáde láyé23 Bélú 2026
  • Ohun tó ṣẹlẹ̀ nínú ìjọ Fountain of Life láàárọ̀ òní rèé22 Bélú 2026

Ilé ẹjọ́ CAS kéde Senegal gẹ́gẹ́ bí ẹgbẹ́ agbábọ́ọ̀lù tó gba ife ẹ̀yẹ AFCON 2025, Morocco mófo

A ti kẹ́fín pé àwọn Janduku fẹ́ lo ìpinnu wa fi dá wàhálà sílẹ̀-NURTW Oyo

Gbajúmọ̀ òṣèré Anike Sinleke jáde láyé

Ohun tó ṣẹlẹ̀ nínú ìjọ Fountain of Life láàárọ̀ òní rèé

Kọ́milẹ́kọ̀ọ́

  • Ṣé lóòótọ́ ni ìjọba Eko gbé owó lílẹ pátákó ìpolongo ìbò jáde ní ₦700m?22 Bélú 2026
  • 1:46Fídíò, Àwọn ìgbésẹ̀ tó yẹ fún ọ láti gbé lọ́jọ́ ìdìbò, Duration 1,4621 Bélú 2026
  • Ijó ló ń jó ló báṣubú lulẹ̀! Awuyewuye lórí ohun tó fa bí obìnrin kan ṣe ṣubúlulẹ̀ níbi tó ti ń jó lóde àríyá19 Bélú 2026
  • Ìjọba UK kéde ohun mẹ́rin tí o gbọ́dọ̀ ṣọ́ra fún tóo bá fẹ́ gba físà kóo má baà kó sọ́wọ́ oníjìbìtì19 Bélú 2026

Ṣé lóòótọ́ ni ìjọba Eko gbé owó lílẹ pátákó ìpolongo ìbò jáde ní ₦700m?

Fídíò, Àwọn ìgbésẹ̀ tó yẹ fún ọ láti gbé lọ́jọ́ ìdìbò, Duration 1,46

Ijó ló ń jó ló báṣubú lulẹ̀! Awuyewuye lórí ohun tó fa bí obìnrin kan ṣe ṣubúlulẹ̀ níbi tó ti ń jó lóde àríyá

Ìjọba UK kéde ohun mẹ́rin tí o gbọ́dọ̀ ṣọ́ra fún tóo bá fẹ́ gba físà kóo má baà kó sọ́wọ́ oníjìbìtì

Ẹ tẹ̀lé wa lórí ìkànnì ayélujára

  • Facebook
  • Instagram
  • WhatsApp
  • 2:29Fídíò, Níṣe ló dà bíi pé wọ́n gba ìyàwó mi lọ́jọ́ tí Taye mi ń lọ sílé ọkọ- Kehinde Afolabi, Duration 2,2924 Bélú 2026
  • 2:30Fídíò, "Ìgbà mẹ́rin ọ̀tọ̀ọ̀tọ̀ ni mo ti kó sọ́wọ́ ajínigbé, ohun tí ojú mí rí rèé", Duration 2,3024 Bélú 2026
  • "Ìgbà mẹ́rin ọ̀tọ̀ọ̀tọ̀ ni mo ti kó sọ́wọ́ ajínigbé, ohun tí ojú mí rí rèé"20 Bélú 2026
  • 2:12Fídíò, Èmi nìkan ni mà á fi òótọ́ inú ṣèjọbà bí mo bá di gómìnà Kwara nítorí mi ò ní bàbá ìsàlẹ̀ - Zakari Muhammed, olùdíje ADC, Duration 2,1219 Bélú 2026
  • Èmi nìkan ni mà á fi òótọ́ inú ṣèjọbà bí mo bá di gómìnà Kwara nítorí mi ò ní bàbá ìsàlẹ̀ - Zakari Muhammed, olùdíje ADC19 Bélú 2026
  • Àwọn ohun tí mo là kọjá ló tọ́ mi sọ́nà tí mò ń tọ̀ báyìí - Dieko, ọmọ Kunle Afolayan sọ̀rọ̀17 Bélú 2026
  • 2:12Fídíò, Wo ìlú tí o ti nílò láti fi BVN, NIN àti ìwé ọjọ́ ìbí rẹ̀ sílẹ̀ láti yá 'power bank' nítorí àìsí iná fún ọdún 18, Duration 2,1217 Bélú 2026
  • 2:22Fídíò, Ọdún mẹ́ẹ̀ẹ́dógún ni mo lò nínú ìgbéyàwó mi àkọ́kọ́ tí ń kò sì rí ọmọ bí níbẹ̀-Toyosi Adesanya, Duration 2,2216 Bélú 2026

Fídíò, Níṣe ló dà bíi pé wọ́n gba ìyàwó mi lọ́jọ́ tí Taye mi ń lọ sílé ọkọ- Kehinde Afolabi, Duration 2,29

Fídíò, "Ìgbà mẹ́rin ọ̀tọ̀ọ̀tọ̀ ni mo ti kó sọ́wọ́ ajínigbé, ohun tí ojú mí rí rèé", Duration 2,30

"Ìgbà mẹ́rin ọ̀tọ̀ọ̀tọ̀ ni mo ti kó sọ́wọ́ ajínigbé, ohun tí ojú mí rí rèé"

Fídíò, Èmi nìkan ni mà á fi òótọ́ inú ṣèjọbà bí mo bá di gómìnà Kwara nítorí mi ò ní bàbá ìsàlẹ̀ - Zakari Muhammed, olùdíje ADC, Duration 2,12

Èmi nìkan ni mà á fi òótọ́ inú ṣèjọbà bí mo bá di gómìnà Kwara nítorí mi ò ní bàbá ìsàlẹ̀ - Zakari Muhammed, olùdíje ADC

Àwọn ohun tí mo là kọjá ló tọ́ mi sọ́nà tí mò ń tọ̀ báyìí - Dieko, ọmọ Kunle Afolayan sọ̀rọ̀

Fídíò, Wo ìlú tí o ti nílò láti fi BVN, NIN àti ìwé ọjọ́ ìbí rẹ̀ sílẹ̀ láti yá 'power bank' nítorí àìsí iná fún ọdún 18, Duration 2,12

Fídíò, Ọdún mẹ́ẹ̀ẹ́dógún ni mo lò nínú ìgbéyàwó mi àkọ́kọ́ tí ń kò sì rí ọmọ bí níbẹ̀-Toyosi Adesanya, Duration 2,22

Ìwádìí kíkún lóríi kókó ìròyìn

  • Bí Olubadan ṣe rọ̀ mí lóyè lọ́wọ́ òṣèlú àti ọ̀tẹ̀ nínú - Aborisade‎Aborishade ni ọdun 2022 ni Ọba Lekan Balogun fi oun joye, lẹyin ti awọn idile oun ti fa oun kalẹ gẹgẹ bi Mogaji wọn.25 Bélú 2026
  • Émi àti ìkejí mi máa ń dáwọ́jọ lu ẹni tó bá fìyà jẹ wa- Taiwo àti Kehinde Afolabi Ìfẹ́ to lagbara lo wa laaarin awọn ibeji naa titi di asiko yii gẹgẹ bi wọn ṣe sọ24 Bélú 2026
  • Nǹkan tó yẹ kí o mọ̀ nípa Postpartum Haemorrhage tí Aisha Lawal sọ pé òun ní lẹ́yìn ìbímọPostpartum Haemorrhage ni aisan to maa n kọlu awọn obinrin lẹyin ti wọn ba bimọ tan, to si ma n mu ki ẹ̀jẹ̀ o dà lara wọn ju bo ṣe yẹ, to si maa n ṣekú pa ọpọlọpọ obinrin.23 Bélú 2026
  • Wo awọn Sẹnetọ ti wọn ko tii gbe aba kankan lọ sile igbimọ asofin Naijiria lati 2023Akọsilẹ StatiSense ṣafihan akọsile ọhun lati ọdun 2023 titi di oṣu Kọkanla, ọdun 2026.24 Bélú 2026
  • Tinubu buwọ́lu ₦250m fún ẹbí àwọn èèyàn tó kú sómi nínú ìjàmbá ọkọ̀ ojú omi ní BayelsaIgbakeji aarẹ Naijiria, Kashim Shettima, lo kede owo naa lasiko to ṣabẹwo si Bayelsa24 Bélú 2026
  • Ìjọba Nàíjíríà bẹ̀rẹ̀ ìgbésẹ̀ láti fòpin sí ìdájọ́ ẹ̀wọ̀n fáwọn tó fẹ́ẹ́ gbẹ̀mí ara wọnLabẹ ofin Naijiria, iwa ọdaran ni ẹnikẹni to ba gbiyanju lati gba ẹmi ara rẹ, ati pe iru ẹni bẹẹ yoo lo to ọdun kan lọgba ẹwọn, tabi ko san owo itanran - iru ẹni bẹẹ si le ṣẹwọn, ko si tun san owo itanran papọ.23 Bélú 2026

Bí Olubadan ṣe rọ̀ mí lóyè lọ́wọ́ òṣèlú àti ọ̀tẹ̀ nínú - Aborisade

‎Aborishade ni ọdun 2022 ni Ọba Lekan Balogun fi oun joye, lẹyin ti awọn idile oun ti fa oun kalẹ gẹgẹ bi Mogaji wọn.

Émi àti ìkejí mi máa ń dáwọ́jọ lu ẹni tó bá fìyà jẹ wa- Taiwo àti Kehinde Afolabi

Ìfẹ́ to lagbara lo wa laaarin awọn ibeji naa titi di asiko yii gẹgẹ bi wọn ṣe sọ

Nǹkan tó yẹ kí o mọ̀ nípa Postpartum Haemorrhage tí Aisha Lawal sọ pé òun ní lẹ́yìn ìbímọ

Postpartum Haemorrhage ni aisan to maa n kọlu awọn obinrin lẹyin ti wọn ba bimọ tan, to si ma n mu ki ẹ̀jẹ̀ o dà lara wọn ju bo ṣe yẹ, to si maa n ṣekú pa ọpọlọpọ obinrin.

Wo awọn Sẹnetọ ti wọn ko tii gbe aba kankan lọ sile igbimọ asofin Naijiria lati 2023

Akọsilẹ StatiSense ṣafihan akọsile ọhun lati ọdun 2023 titi di oṣu Kọkanla, ọdun 2026.

Tinubu buwọ́lu ₦250m fún ẹbí àwọn èèyàn tó kú sómi nínú ìjàmbá ọkọ̀ ojú omi ní Bayelsa

Igbakeji aarẹ Naijiria, Kashim Shettima, lo kede owo naa lasiko to ṣabẹwo si Bayelsa

Ìjọba Nàíjíríà bẹ̀rẹ̀ ìgbésẹ̀ láti fòpin sí ìdájọ́ ẹ̀wọ̀n fáwọn tó fẹ́ẹ́ gbẹ̀mí ara wọn

Labẹ ofin Naijiria, iwa ọdaran ni ẹnikẹni to ba gbiyanju lati gba ẹmi ara rẹ, ati pe iru ẹni bẹẹ yoo lo to ọdun kan lọgba ẹwọn, tabi ko san owo itanran - iru ẹni bẹẹ si le ṣẹwọn, ko si tun san owo itanran papọ.

Àwọn Ìròyìn Kàyééfì míràn

  • Davido, Asake, Tems, Burna Boy, Ayra Starr àtàwọn tórúkọ wọn jáde fún àmì ẹ̀yẹ Grammy ọdún 202716 Bélú 2026
  • Ibi tí wọ́n bí mi sí kò jìnà síbi tí wọ́n ti ń ta igbó, àánú ló kó mi yọ tí mo fi di akọrin ẹ̀mí - Esther Igbekele13 Bélú 2026
  • Ẹ má sunkún tí mo bá kú, àrá máa sán pa ẹni tó bá ké nítorí mi- Oba Solomon7 Bélú 2026
  • Kí ni pàtàkì àyẹyẹ àyàjọ́ Ogbomoso tó máa ń wáyé lọ́dọdún?7 Bélú 2026

Davido, Asake, Tems, Burna Boy, Ayra Starr àtàwọn tórúkọ wọn jáde fún àmì ẹ̀yẹ Grammy ọdún 2027

Ibi tí wọ́n bí mi sí kò jìnà síbi tí wọ́n ti ń ta igbó, àánú ló kó mi yọ tí mo fi di akọrin ẹ̀mí - Esther Igbekele

Ẹ má sunkún tí mo bá kú, àrá máa sán pa ẹni tó bá ké nítorí mi- Oba Solomon

Kí ni pàtàkì àyẹyẹ àyàjọ́ Ogbomoso tó máa ń wáyé lọ́dọdún?

Ife Ẹ̀yẹ Àgbáyé 2026/Eré Ìdárayá

  • Kí ló mú kí géèmù GTA 6 máa tà wàràwàrà láàárín ọjọ́ díẹ̀ tó jáde?21 Bélú 2026
  • Àwọn afurasí adigunjalè ṣèkọlù sí Segun Odegbami nílé rẹ̀ l'Abeokuta, ọlọ́pàá bẹ̀rẹ̀ ìwádìí20 Bélú 2026
  • Ta ni Suleiman Mubarak, agbábọ́ọ̀lù Super Eagles tuntun tí yóò kópa nínú ifẹsẹ̀wọnsẹ̀ pẹ̀lú Tanzania?13 Bélú 2026
  • 0:54Fídíò, Ọmọ Naijiria meji gba ami ẹyẹ Wura fun ère sisa níbi idije Olympic àwọn ọdọ, Duration 0,5410 Bélú 2026
  • Wo àwọn kókó márùn-un tó jẹ́ kí Flamingos gba ife ẹ̀yẹ U-17 fún ìgbà àkọ́kọ́8 Bélú 2026
  • Ẹgbẹ́ agbábọ̀ọ̀lù Flamingos ti Nàíjíríà pegedé fún ipele àṣekágbá ìdíje U-17 ti àwọn obìnrin fún ìgbà àkọ́kọ́5 Bélú 2026
  • 2:15Fídíò, Ẹ wo ìbẹ̀rẹ̀ ayé Aisha Yusuf Ojora, ọmọ atàpátadìde tò di igbákejì akọ́nimọ̀ọ́gbá fun Super Falcons, Duration 2,1531 Ọ̀wàrà 2026
  • Ìjọba àpapọ̀ fẹ́ máa fún àwọn ọmọ Naijiria tí ìṣẹ́ ń ṣẹ́ ní 50,000 lóṣù31 Ọ̀wàrà 2026

Kí ló mú kí géèmù GTA 6 máa tà wàràwàrà láàárín ọjọ́ díẹ̀ tó jáde?

Àwọn afurasí adigunjalè ṣèkọlù sí Segun Odegbami nílé rẹ̀ l'Abeokuta, ọlọ́pàá bẹ̀rẹ̀ ìwádìí

Ta ni Suleiman Mubarak, agbábọ́ọ̀lù Super Eagles tuntun tí yóò kópa nínú ifẹsẹ̀wọnsẹ̀ pẹ̀lú Tanzania?

Fídíò, Ọmọ Naijiria meji gba ami ẹyẹ Wura fun ère sisa níbi idije Olympic àwọn ọdọ, Duration 0,54

Wo àwọn kókó márùn-un tó jẹ́ kí Flamingos gba ife ẹ̀yẹ U-17 fún ìgbà àkọ́kọ́

Ẹgbẹ́ agbábọ̀ọ̀lù Flamingos ti Nàíjíríà pegedé fún ipele àṣekágbá ìdíje U-17 ti àwọn obìnrin fún ìgbà àkọ́kọ́

Fídíò, Ẹ wo ìbẹ̀rẹ̀ ayé Aisha Yusuf Ojora, ọmọ atàpátadìde tò di igbákejì akọ́nimọ̀ọ́gbá fun Super Falcons, Duration 2,15

Ìjọba àpapọ̀ fẹ́ máa fún àwọn ọmọ Naijiria tí ìṣẹ́ ń ṣẹ́ ní 50,000 lóṣù

Ìròyìn tí àwọn ènìyàn fẹ́ràn jùlọ

  1. 1NÍ YÀJÓYÀJÓ Kí ni ó bí ètò ìdìbò ìgbáradì tó ń lọ lọ́wọ́ lónìí ní Nàìjíríà?
  2. 2Ta ni Idiat Adebule, aṣòfin Eko tó jáde láyé?
  3. 3''Olorì lè kúrò ní àáfin àmọ́ ààfin kìí fi Olorì sílẹ̀,'' Olorì Silekunola sọ̀rọ̀ lórí i bó ṣe pàdé kábíyèsí àti bó ṣe kúrò láàfin Ooni
  4. 4Mi ò fẹ yín, bẹ́ẹ̀ ni mi ò fìwé pè ẹ̀yin ọmọ ẹgbẹ́ awakọ̀ NURTW síbi ìbúrawọlé mi - Gomina Ademola Adeleke
  5. 5Ohun márùn ún ọ̀tọ̀tọ̀ tí Adeleke ní òun yóò ṣe fún ìpínlẹ̀ Osun ní sáà kejì rẹ̀ lórí oyè
  6. 6Ìjọba ológun yí àdéhùn padà ní Guinea-Bissau, wọ́n ló di 2028 káwọn tóó gbé ìjọba fún alágbádá
  7. 7Ẹ gba àlàáfíà láàyè, máà fún ẹbí olóògbé kọ̀ọ̀kan ní mílíọ̀nù méjì Náírà - Gómìnà Bago ti Niger
  8. 8Tinubu ló sanwó ta fi gbé òkú Moji Olaiya wá láti òke òkun - Jide KosokoTí a mú dójú ìwọ̀n gbẹ̀yìn ní: 2 Agẹmo 2022
  9. 9Ohun tí mo rí, ẹ̀yin kò ri ní mo ṣe di èèyàn burúkú lójú àwọn olóṣèlú - Sunday IgbohoTí a mú dójú ìwọ̀n gbẹ̀yìn ní: 6 Òkùdu 2022
  10. 10Wo awọn ọmọ Naijiria 157 ti ijọba Amẹrika fẹẹ da pada sile lori ẹsun iwa ọdaran